Orin Solomoni 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbé mi lé oókan àyà rẹ bí èdìdì ìfẹ́,bí èdìdì, ní apá rẹ;nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú.Owú jíjẹ burú, àfi bí isà òkú.A máa jó bí iná,bí ọwọ́ iná tí ó lágbára.

Orin Solomoni 8

Orin Solomoni 8:1-14