Ọ̀pọ̀ omi kò lè pa iná ìfẹ́,ìgbì omi kò sì lè tẹ̀ ẹ́ rì.Bí eniyan bá gbìyànjú láti fi gbogbo nǹkan ìní rẹ̀ ra ìfẹ́,ẹ̀tẹ́ ni yóo fi gbà.