Orin Solomoni 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ní ń bọ̀ láti inú aṣálẹ̀ yìí,tí ó fara ti olùfẹ́ rẹ̀?Lábẹ́ igi èso ápù ni mo ti jí ọ,níbi tí ìyá rẹ ti rọbí rẹ,níbi tí ẹni tí ó bí ọ ti rọbí.

Orin Solomoni 8

Orin Solomoni 8:1-12