Orin Dafidi 99:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. OLUWA Ọlọrun wa, o dá wọn lóhùn;Ọlọrun tíí dáríjì ni ni o jẹ́ fún wọn;ṣugbọn ó gbẹ̀san ìwàkiwà wọn.

9. Ẹ yin OLUWA, Ọlọrun wa,kí ẹ sì jọ́sìn níbi òkè mímọ́ rẹ̀;nítorí pé mímọ́ ni OLUWA Ọlọrun wa.

Orin Dafidi 99