Orin Dafidi 98:9 BIBELI MIMỌ (BM)

níwájú OLUWA, nítorí pé ó ń bọ̀ wá ṣe ìdájọ́ ayé.Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé;yóo sì fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.

Orin Dafidi 98

Orin Dafidi 98:1-9