Orin Dafidi 99:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA jọba, kí àwọn orílẹ̀-èdè wárìrì;ó gúnwà lórí àwọn kerubu; kí ilẹ̀ mì tìtì.

Orin Dafidi 99

Orin Dafidi 99:1-3