Orin Dafidi 99:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yin OLUWA, Ọlọrun wa,kí ẹ sì jọ́sìn níbi òkè mímọ́ rẹ̀;nítorí pé mímọ́ ni OLUWA Ọlọrun wa.

Orin Dafidi 99

Orin Dafidi 99:1-9