Orin Dafidi 99:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Jẹ́ kí wọ́n yin orúkọ rẹ tí ó tóbi tí ó sì lẹ́rù,mímọ́ ni OLUWA!

4. Ọba alágbára, ìwọ tí o fẹ́ràn òdodo,o ti fi ìdí ẹ̀tọ́ múlẹ̀;o ti dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ ati òdodo ní ilẹ̀ Jakọbu.

5. Ẹ yin OLUWA, Ọlọrun wa,ẹ jọ́sìn níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀;mímọ́ ni OLUWA!

Orin Dafidi 99