Orin Dafidi 99:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba alágbára, ìwọ tí o fẹ́ràn òdodo,o ti fi ìdí ẹ̀tọ́ múlẹ̀;o ti dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ ati òdodo ní ilẹ̀ Jakọbu.

Orin Dafidi 99

Orin Dafidi 99:1-7