Orin Dafidi 99:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA jọba, kí àwọn orílẹ̀-èdè wárìrì;ó gúnwà lórí àwọn kerubu; kí ilẹ̀ mì tìtì.

2. OLUWA tóbi ní Sioni,ó sì jọba lórí gbogbo orílẹ̀-èdè.

3. Jẹ́ kí wọ́n yin orúkọ rẹ tí ó tóbi tí ó sì lẹ́rù,mímọ́ ni OLUWA!

Orin Dafidi 99