Orin Dafidi 71:23-24 BIBELI MIMỌ (BM)

23. N óo máa kígbe fún ayọ̀,nígbà tí mo bá ń kọ orin ìyìn sí ọ;ẹ̀mí mi tí o ti kó yọ, yóo ké igbe ayọ̀.

24. Ẹnu mi yóo ròyìn iṣẹ́ rẹ tọ̀sán-tòru,nítorí a ti ṣẹgun àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára,a sì ti dójú tì wọ́n.

Orin Dafidi 71