Orin Dafidi 71:23 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa kígbe fún ayọ̀,nígbà tí mo bá ń kọ orin ìyìn sí ọ;ẹ̀mí mi tí o ti kó yọ, yóo ké igbe ayọ̀.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:18-24