Orin Dafidi 71:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi náà óo máa fi hapu yìn ọ́,nítorí òtítọ́ rẹ, Ọlọrun mi;n óo máa fi ohun èlò orin yìn ọ́,ìwọ ẹni mímọ́ Israẹli.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:17-24