Orin Dafidi 71:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu mi yóo ròyìn iṣẹ́ rẹ tọ̀sán-tòru,nítorí a ti ṣẹgun àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára,a sì ti dójú tì wọ́n.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:23-24