Orin Dafidi 70:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí,yára wá sọ́dọ̀ mi, Ọlọrun!Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi ati olùgbàlà mi,má pẹ́ OLÚWA.

Orin Dafidi 70

Orin Dafidi 70:1-5