Orin Dafidi 70:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀ nítorí rẹ,kí inú wọn sì máa dùn,kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹ máa wí nígbà gbogbo pé,“Ọlọrun tóbi!”

Orin Dafidi 70

Orin Dafidi 70:2-5