Orin Dafidi 45:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Aṣọ rẹ kún fún òórùn oríṣìíríṣìí turari,láti inú ààfin tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ni wọ́n tí ń fi ohun èlò ìkọrin olókùn dá ọ lára yá.

Orin Dafidi 45

Orin Dafidi 45:5-17