Orin Dafidi 45:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ọba wà lára àwọn obinrin inú àgbàlá rẹ,ayaba dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ,ó fi ojúlówó wúrà ṣe ọ̀ṣọ́ sára.

Orin Dafidi 45

Orin Dafidi 45:3-10