Orin Dafidi 45:7 BIBELI MIMỌ (BM)

O fẹ́ràn òdodo, o sì kórìíra ìwà ìkànítorí náà ni Ọlọrun, àní Ọlọrun rẹ, ṣe fi àmì òróró yàn ọ́.Àmì òróró ayọ̀ ni ó fi gbé ọ gaju àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ lọ.

Orin Dafidi 45

Orin Dafidi 45:1-16