Orin Dafidi 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti fi ọ̀nà ìyè hàn mí;ayọ̀ kíkún ń bẹ ní iwájú rẹ,ìgbádùn àìlópin sì ń bẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.

Orin Dafidi 16

Orin Dafidi 16:9-11