Orin Dafidi 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí o kò ní gbàgbé mi sí ipò òkú,bẹ́ẹ̀ ni o kò ní jẹ́ kí ẹni tí ó fi tọkàntọkàn sìn ọ́ rí ìdíbàjẹ́.

Orin Dafidi 16

Orin Dafidi 16:3-11