Orin Dafidi 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbọ́ tèmi OLUWA, àre ni ẹjọ́ mi;fi ìtara gbọ́ igbe mi.Fetí sí adura mi nítorí kò sí ẹ̀tàn ní ẹnu mi.

Orin Dafidi 17

Orin Dafidi 17:1-8