Orin Dafidi 16:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Pa mí mọ́ Ọlọrun, nítorí ìwọ ni mo sá di.

2. Mo wí fún ọ, OLUWA, pé, “Ìwọ ni Oluwa mi;ìwọ nìkan ni orísun ire mi.”

3. Nípa àwọn eniyan mímọ́ tí ó wà nílẹ̀ yìí,wọ́n jẹ́ ọlọ́lá tí àwọn eniyan fẹ́ràn.

Orin Dafidi 16