Orin Dafidi 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í yáni lówó kí ó gba èlé,kìí sìí gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ́wọ́ aláìṣẹ̀.Ẹni tí ó bá ṣe nǹkan wọnyi,ẹsẹ̀ rẹ̀ kò ní yẹ̀ laelae.

Orin Dafidi 15

Orin Dafidi 15:1-5