Orin Dafidi 16:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Pa mí mọ́ Ọlọrun, nítorí ìwọ ni mo sá di.

2. Mo wí fún ọ, OLUWA, pé, “Ìwọ ni Oluwa mi;ìwọ nìkan ni orísun ire mi.”

Orin Dafidi 16