Orin Dafidi 148:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. ẹ̀yin ọdọmọkunrin ati ọlọ́mọge,ẹ̀yin ọmọde ati ẹ̀yin àgbààgbà.

13. Ẹ jẹ́ kí wọn yin orúkọ OLUWA,nítorí pé orúkọ rẹ̀ nìkan ni ó ga jù;ògo rẹ̀ sì ga ju ayé ati ọ̀run lọ.

14. Ó ti fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára,ó sì fún àwọn eniyan rẹ̀ mímọ́ ní ìyìn;ó fún àwọn eniyan Israẹli, tí ó wà lẹ́bàá ọ̀dọ̀ rẹ̀.Ẹ yin OLUWA!

Orin Dafidi 148