Orin Dafidi 148:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí wọn yin orúkọ OLUWA,nítorí pé orúkọ rẹ̀ nìkan ni ó ga jù;ògo rẹ̀ sì ga ju ayé ati ọ̀run lọ.

Orin Dafidi 148

Orin Dafidi 148:7-14