Ó ti fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára,ó sì fún àwọn eniyan rẹ̀ mímọ́ ní ìyìn;ó fún àwọn eniyan Israẹli, tí ó wà lẹ́bàá ọ̀dọ̀ rẹ̀.Ẹ yin OLUWA!