Orin Dafidi 149:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yin OLUWA!Ẹ kọ orin titun sí OLUWA,ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́.

Orin Dafidi 149

Orin Dafidi 149:1-9