Orin Dafidi 14:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Òmùgọ̀ sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé, “Ọlọrun kò sí.”Wọ́n bàjẹ́, ohun ìríra ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn,kò sì sí ẹnìkan ninu wọn tí ń ṣe rere.

2. OLUWA bojú wo ilẹ̀, láti ọ̀run wá,ó wo àwọn ọmọ eniyan,láti mọ̀ bí àwọn kan bá wà tí wọ́n gbọ́n,tí wọn ń wá Ọlọrun.

Orin Dafidi 14