Orin Dafidi 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bojú wo ilẹ̀, láti ọ̀run wá,ó wo àwọn ọmọ eniyan,láti mọ̀ bí àwọn kan bá wà tí wọ́n gbọ́n,tí wọn ń wá Ọlọrun.

Orin Dafidi 14

Orin Dafidi 14:1-7