Orin Dafidi 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Òmùgọ̀ sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé, “Ọlọrun kò sí.”Wọ́n bàjẹ́, ohun ìríra ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn,kò sì sí ẹnìkan ninu wọn tí ń ṣe rere.

Orin Dafidi 14

Orin Dafidi 14:1-2