Orin Dafidi 133:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dàbí ìrì òkè Herimoni,tí ó sẹ̀ sórí òkè Sioni.Níbẹ̀ ni OLUWA ti ṣe ìlérí ibukun,àní, ìyè ainipẹkun.

Orin Dafidi 133

Orin Dafidi 133:1-3