Orin Dafidi 134:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá, ẹ yin OLUWA,gbogbo ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀,gbogbo ẹ̀yin tí ń sìn ín ninu ilé rẹ̀ lóru.

Orin Dafidi 134

Orin Dafidi 134:1-3