Orin Dafidi 133:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dàbí òróró iyebíye tí a dà síni lórí,tí ó ṣàn dé irùngbọ̀n;bí ó ti ṣàn dé irùngbọ̀n Aaroni,àní, títí dé ọrùn ẹ̀wù rẹ̀.

Orin Dafidi 133

Orin Dafidi 133:1-3