Orin Dafidi 100:4-5 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́,kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn.Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀.

5. Nítorí OLUWA ṣeun;ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae,òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.

Orin Dafidi 100