Orin Dafidi 100:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́,kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn.Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀.

Orin Dafidi 100

Orin Dafidi 100:2-5