Orin Dafidi 100:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ̀ dájú pé OLUWA ni Ọlọrun,òun ló dá wa, òun ló ni wá;àwa ni eniyan rẹ̀,àwa sì ni agbo aguntan rẹ̀.

Orin Dafidi 100

Orin Dafidi 100:2-5