Jeremaya 31:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìrètí ń bẹ fún ọ lẹ́yìn ọ̀la,àwọn ọmọ rẹ yóo pada sí orílẹ̀-èdè wọn.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:9-23