Jeremaya 31:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo gbọ́ bí Efuraimu tí ń kẹ́dùn,ó ní: ‘O ti bá mi wí, ìbáwí sì dùn mí,bí ọmọ mààlúù tí a kò kọ́.Mú mi pada, kí n lè pada sí ààyè mi,nítorí pé ìwọ ni OLUWA, Ọlọrun mi.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:9-24