Jeremaya 31:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé lẹ́yìn tí mo ṣáko lọ, mo ronupiwada;lẹ́yìn tí o kọ́ mi lọ́gbọ́n, ń ṣe ni mo káwọ́ lérí.Ojú tì mí, ìdààmú sì bá mi,nítorí ìtìjú ohun tí mo ṣe nígbà èwe mi dé bá mi.’

Jeremaya 31

Jeremaya 31:10-28