Jeremaya 31:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣé ọmọ mi ọ̀wọ́n ni Efuraimu ni?Ṣé ọmọ mi àtàtà ni?Nítorí bí mo tí ń sọ̀rọ̀ ibinu sí i tó, sibẹ mò ń ranti rẹ̀,nítorí náà ọkàn rẹ̀ ń fà mí;dájúdájú n óo ṣàánú rẹ̀.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:16-22