Jeremaya 31:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ri òpó mọ́lẹ̀ lọ fún ara yín,ẹ sàmì sí àwọn ojú ọ̀nà.Ẹ wo òpópónà dáradára, ẹ fiyèsí ọ̀nà tí ẹ gbà lọ.Ẹ yipada, ẹ̀yin ọmọ Israẹli,ẹ pada sí àwọn ìlú yín wọnyi.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:14-29