Jeremaya 31:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìgbà wo ni ẹ óo ṣe iyèméjì dà, ẹ̀yin alainigbagbọ wọnyi?Nítorí OLUWA ti dá ohun titun sórí ilẹ̀ ayé,bíi kí obinrin máa dáàbò bo ọkunrin.”

Jeremaya 31

Jeremaya 31:13-26