Jeremaya 31:23 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, “Lẹ́ẹ̀kan sí i, wọn yóo tún máa lo gbolohun yìí ní ilẹ̀ Juda ati ní àwọn ìlú rẹ̀, nígbà tí mo bá dá ire wọn pada, wọn óo máa wí pé,‘OLUWA yóo bukun ọ, ìwọ òkè mímọ́ Jerusalẹmu,ibùgbé olódodo.’

Jeremaya 31

Jeremaya 31:22-24