Jeremaya 31:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo máa gbé àwọn ìlú Juda ati àwọn agbègbè rẹ̀ pẹlu àwọn àgbẹ̀ ati àwọn darandaran.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:15-31