Jeremaya 31:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Má sọkún mọ́, nu ojú rẹ nù,nítorí o óo jẹ èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.Àwọn ọmọ rẹ yóo pada wá láti ilẹ̀ ọ̀tá wọn.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:9-25