Jeremaya 31:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“A gbọ́ ohùn kan ní Rama,ariwo ẹkún ẹ̀dùn ati arò ni.Rakẹli ń sọkún àwọn ọmọ rẹ̀,wọ́n ṣìpẹ̀ fún un títí, kò gbà,nítorí àwọn ọmọ rẹ̀ tí kò sí mọ́.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:10-25