Jeremaya 31:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún àwọn alufaa ní ọpọlọpọ oúnjẹ,n óo sì fi oore mi tẹ́ àwọn eniyan mi lọ́rùn.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Jeremaya 31

Jeremaya 31:7-24