Num 26:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li awọn ọmọ Benjamini gẹgẹ bi idile wọn: ati awọn ti a kà ninu wọn jẹ́ ẹgba mejilelogun o le ẹgbẹjọ.

Num 26

Num 26:40-45